Tàn ìròyìn nípa Ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ pẹ̀lú ìrọ̀rùn.

Tàn ìròyìn nípa Ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ pẹ̀lú ìrọ̀rùn.
https://bible.com/events/2342
callout

Lẹ́yìn tí o bá ti ṣe ètò Ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ, tí o sì ti ṣe tán láti pín-in, Ìṣẹ̀lẹ̀ fún ọ ní ìjápọ̀ tí o lè lò lórí gbogbo àwọn ìkànnì àjọlò rẹ, nínú ìjápọ̀ ímeèlì rẹ, àti kódà lórí ìtàkùn ní àsìkò ìsìn tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ. Ní ìgbà tí ẹnìkan tí ó ní Ẹ̀rọ Bíbélì bá lọ sí ìjápọ̀ rẹ, Ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ yóò ṣí ní tààràtà nínú ẹ̀rọ. Bí wọn kò bá ní Ẹ̀rọ Bíbélì, wọn yóò rí Ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ ní Bible.com, pẹ̀lú àwọn ìtọ́ka láti ṣe ìgbàkalẹ̀ ẹ̀rọ náà bí wọ́n bá fẹ́.

Àwọn ohun èlò ọ̀fẹ́ láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ọ pẹ̀lú Ìṣẹ̀lẹ̀

Wo fídíò nípa bí o ṣe lè yí padà sí Ìṣẹ̀lẹ̀

Gbígbà ẹ̀dà fáìlì jáde àwọn ohun ìní wọ̀nyí láti ta àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ lórí Facebook, Twitter, àti Instagram

Gbígbà ẹ̀dà fáìlì jáde àwọn àwòrán ojúewé yìí àti ìwé ìkésíni láti ta àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ nínú ìjọ tàbí àjọ rẹ

Sé o tún ńwá àwọn ohun èlò ọ̀fẹ́ sí? Wáa nínú àwọn ẹgbẹgbẹ̀rún ìwàásù, àwọn ohun èlò ọmọdé, ojúlówó ohun èlò tí a lè fi sẹ̀dá nkan àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ ní sí.ìjọ