Sef 3:1-2
Sef 3:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
EGBE ni fun ọlọ̀tẹ ati alaimọ́, fun ilu aninilara nì. On kò fetisi ohùn na; on kò gba ẹkọ́; on kò gbẹkẹ̀le Oluwa; on kò sunmọ ọdọ Ọlọrun rẹ̀.
Pín
Kà Sef 3EGBE ni fun ọlọ̀tẹ ati alaimọ́, fun ilu aninilara nì. On kò fetisi ohùn na; on kò gba ẹkọ́; on kò gbẹkẹ̀le Oluwa; on kò sunmọ ọdọ Ọlọrun rẹ̀.