LI oṣù kẹjọ, li ọdun keji Dariusi, li ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Sekariah wá, ọmọ Berekiah ọmọ Iddo woli, pe
Ní oṣù kẹjọ, ọdún keji ìjọba Dariusi, OLUWA rán wolii Sakaraya, ọmọ Berekaya, ọmọ Ido, sí àwọn ọmọ Israẹli; ó ní
Ní oṣù kẹjọ ọdún kejì ọba Dariusi, ọ̀rọ̀ OLúWA tọ wòlíì Sekariah ọmọ Berekiah, ọmọ Iddo pé
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò