Tit 3:1 - Compare All Versions
Tit 3:1 YBCV (Bibeli Mimọ)
MÃ rán wọn leti lati mã tẹriba fun awọn ijoye, ati fun awọn alaṣẹ, lati mã gbọ́ ti wọn, ati lati mã mura si iṣẹ rere gbogbo
Pín
Tit 3 YBCVTit 3:1 YCE (Yoruba Bible)
Máa rán wọn létí kí wọn máa tẹríba fún ìjọba ati àwọn aláṣẹ, kí wọn máa gbọ́ràn sí wọn lẹ́nu, kí wọn sì múra láti máa ṣe iṣẹ́ rere gbogbo.
Pín
Tit 3 YCETit 3:1 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rán àwọn ènìyàn náà létí láti máa tẹríba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ. Kí wọn ṣe ìgbọ́ràn nígbà gbogbo, kí wọn sì múra fún iṣẹ́ rere gbogbo.
Pín
Tit 3 BMYO