O. Sol 8:6
O. Sol 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Gbé mi sí àyà rẹ bí èdìdì bí èdìdì lé apá rẹ; nítorí ìfẹ́ lágbára bí ikú, ìjowú sì le bí isà òkú jíjò rẹ̀ rí bí jíjò iná, gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́-iná OLúWA.
Pín
Kà O. Sol 8O. Sol 8:6 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbe mi ka aiya rẹ bi edidi, bi edidi le apá rẹ: nitori ifẹ lagbara bi ikú; ijowu si le bi isa-okú; jijo rẹ̀ dabi jijo iná, ani ọwọ iná Oluwa.
Pín
Kà O. Sol 8