O. Sol 6:10
O. Sol 6:10 Yoruba Bible (YCE)
Ta ni ń yọ bọ̀ bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ yìí, tí ó mọ́ bí ọjọ́, tí ó lẹ́wà bí òṣùpá. Tí ó sì bani lẹ́rù, bí àwọn ọmọ ogun tí wọn dira ogun?
Pín
Kà O. Sol 6O. Sol 6:10 Bibeli Mimọ (YBCV)
Tali ẹniti ntàn jàde bi owurọ, ti o li ẹwà bi oṣupa, ti o mọ́ bi õrun, ti o si li ẹ̀ru bi ogun pẹlu ọpagun?
Pín
Kà O. Sol 6