O. Sol 2:3-4
O. Sol 2:3-4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi igi eleso lãrin awọn igi igbẹ, bẹ̃li olufẹ mi ri lãrin awọn ọmọkunrin. Emi fi ayọ̀ nla joko labẹ ojiji rẹ̀, eso rẹ̀ si dùn mọ mi li ẹnu. O mu mi wá si ile ọti-waini, Ifẹ si ni ọpagun rẹ̀ lori mi.
Pín
Kà O. Sol 2