O. Sol 1:4
O. Sol 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Fà mí lọ pẹ̀lú rẹ, kí a lọ kíákíá ọba ti mú mi wá sínú yàrá rẹ̀. Àwa yọ̀ inú wa sì dùn sí ọ; a gbé ìfẹ́ rẹ ga ju ọtí wáìnì lọ. Wọ́n fẹ́ ọ nítòótọ́!
Pín
Kà O. Sol 1O. Sol 1:4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Fà mi, awa o sare tọ̀ ọ: ọba ti mu mi wá sinu iyẹwù rẹ̀: awa o yọ̀, inu wa o si dùn si ọ, awa o ranti ifẹ rẹ jù ọti-waini lọ: nwọn fẹ ọ nitõtọ.
Pín
Kà O. Sol 1