Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rut 4:13YBCV(Bibeli Mimọ)
Boasi si mú Rutu, on si di aya rẹ̀; nigbati o si wọle tọ̀ ọ, OLUWA si mu ki o lóyun, o si bi ọmọkunrin kan.
Rut 4:13BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni Boasi ṣe mú Rutu, tí ó sì di aya rẹ̀. Nígbà náà ni ó wọlé tọ aya rẹ̀, OLúWA sì mú kí ó lóyún, ó sì bí ọmọ ọkùnrin kan.
Rut 4:13YCE(Yoruba Bible)
Boasi bá ṣú Rutu lópó, Rutu sì di aya rẹ̀. Nígbà tí Boasi bá a lòpọ̀, ó lóyún, ó bí ọmọkunrin kan.