Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 9:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori ọ̀rọ ileri li eyi, Niwoyi amọdun li emi ó wá; Sara yio si ni ọmọkunrin.
Pín
Rom 9YBCVRom 9:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ọ̀rọ̀ ìlérí ni èyí: “Ní ìwòyí àmọ́dún ni èmi yóò wá, Sara yóò sì ní ọmọ ọkùnrin.”
Pín
Rom 9BMYORom 9:9YCE(Yoruba Bible)
Nítorí báyìí ni ọ̀rọ̀ ìlérí náà: “Nígbà tí mo bá pada wá ní ìwòyí àmọ́dún, Sara yóo ti bí ọmọkunrin kan.”
Pín
Rom 9YCE