Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 9:27YBCV(Bibeli Mimọ)
Isaiah si kigbe nitori Israeli pe, Bi iye awọn ọmọ Israeli bá ri bi iyanrin okun, apakan li a ó gbala.
Pín
Rom 9YBCVRom 9:27BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Isaiah sì kígbe nítorí Israẹli pé: “Bí iye àwọn ọmọ Israẹli bá rí bí iyanrìn Òkun, apá kan ni ó gbàlà.
Pín
Rom 9BMYORom 9:27YCE(Yoruba Bible)
Aisaya náà kéde nípa Israẹli pé, “Bí àwọn ọmọ Israẹli tilẹ̀ pọ̀ bí iyanrìn òkun, sibẹ díẹ̀ péré ni a óo gbà là.
Pín
Rom 9YCE