Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 9:25YBCV(Bibeli Mimọ)
Bi o ti wi pẹlu ni Hosea pe, Emi ó pè awọn ti kì iṣe enia mi, li enia mi, ati ẹniti ki iṣe ayanfẹ li ayanfẹ.
Pín
Rom 9YBCVRom 9:25BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó ti wí pẹ̀lú ní Hosea pé, “Èmi ó pe àwọn tí kì í ṣe ènìyàn mi, ní ‘ènìyàn mi’, àti ẹni tí kí í ṣe àyànfẹ́ ní ‘àyànfẹ́.’ ”
Pín
Rom 9BMYORom 9:25YCE(Yoruba Bible)
bí ó ti sọ ninu Ìwé Hosia pé, “Èmi yóo pe àwọn tí kì í ṣe eniyan mi ní ‘Eniyan mi.’ N óo sì pe àwọn orílẹ̀-èdè tí n kò náání ní ‘Àyànfẹ́ mi.’
Pín
Rom 9YCE