Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 8:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Ki a le mu ododo ofin ṣẹ ninu awa, ti kò rin nipa ti ara, bikoṣe nipa ti Ẹmí.
Pín
Rom 8YBCVRom 8:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
kí a lè mú òdodo òfin ṣẹ, nínú wa, nítorí tí àwa yé gẹ́gẹ́ bí ohun ti ara, bí kò ṣe gẹ́gẹ́ bí ohun ti Ẹ̀mí.
Pín
Rom 8BMYORom 8:4YCE(Yoruba Bible)
Ọlọrun ṣe èyí kí á lè tẹ̀lé ìlànà Òfin ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́, àní àwa tí ìhùwàsí wa kì í ṣe bíi tí ẹni tí ẹran-ara ń lò ṣugbọn bí àwọn ẹni tí Ẹ̀mí ń darí.
Pín
Rom 8YCE