Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Rom 7:14YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitori awa mọ̀ pe ohun ẹmí li ofin: ṣugbọn ẹni ti ara li emi, ti a ti tà sabẹ ofin.

Rom 7:14BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí àwa mọ̀ pé ohun ẹ̀mí ni òfin, ṣùgbọ́n ẹni ti ara ni èmi, tí a ti tà sábẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.

Rom 7:14YCE(Yoruba Bible)

Àwa mọ̀ dájú pé Òfin jẹ́ nǹkan ti Ẹ̀mí. Ṣugbọn èmi jẹ́ eniyan ẹlẹ́ran-ara, tí a ti tà lẹ́rú fún ẹ̀ṣẹ̀.