Rom 7:10-11
Rom 7:10-11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ofin ti a ṣe fun ìye, eyi li emi si wa ri pe o jẹ fun ikú. Nitori ẹ̀ṣẹ ti ipa ofin ri aye, o tàn mi jẹ, o si ti ipa rẹ̀ lù mi pa.
Pín
Kà Rom 7Ofin ti a ṣe fun ìye, eyi li emi si wa ri pe o jẹ fun ikú. Nitori ẹ̀ṣẹ ti ipa ofin ri aye, o tàn mi jẹ, o si ti ipa rẹ̀ lù mi pa.