Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 6:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori awa mọ̀ pé bi a ti jí Kristi dide kuro ninu okú, kò ni ikú mọ́; ikú kò ni ipa lori rẹ̀ mọ́.
Pín
Rom 6YBCVRom 6:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwa mọ̀ pé Kristi ti jí dìde kúrò nínú òkú. Òun kò sì ní kú mọ́. Ikú kò sì lè ní agbára lórí rẹ̀ mọ́.
Pín
Rom 6BMYORom 6:9YCE(Yoruba Bible)
A mọ̀ pé Kristi tí a ti jí dìde kúrò ninu òkú, kò tún ní kú mọ́; ikú kò sì lè jọ̀gá lórí rẹ̀ mọ́.
Pín
Rom 6YCE