Rom 6:14
Rom 6:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ẹ̀ṣẹ kì yio ni ipa lori nyin: nitori ẹnyin kò si labẹ ofin, bikoṣe labẹ ore-ọfẹ.
Pín
Kà Rom 6Rom 6:14 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ má jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ di ọ̀gá yín, nítorí ẹ kò sí lábẹ́ Òfin; abẹ́ oore-ọ̀fẹ́ ni ẹ wà.
Pín
Kà Rom 6