Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Rom 4:22YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitorina li a si ṣe kà a si ododo fun u.

Rom 4:22BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí náà ni a sì ṣe kà á sí òdodo fún un.

Rom 4:22YCE(Yoruba Bible)

Ìdí rẹ̀ nìyí tí Ọlọrun fi ka igbagbọ rẹ̀ sí iṣẹ́ rere fún un.