Rom 3:1-2
Rom 3:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
NJẸ anfani ki ha ni ti Ju? tabi kini ère ilà kíkọ? Pipọ lọna gbogbo; ekini, nitoripe awọn li a fi ọ̀rọ Ọlọrun le lọwọ.
Pín
Kà Rom 3NJẸ anfani ki ha ni ti Ju? tabi kini ère ilà kíkọ? Pipọ lọna gbogbo; ekini, nitoripe awọn li a fi ọ̀rọ Ọlọrun le lọwọ.