Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 3:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ àǹfààní wo ní Júù ní? Tàbí kín ni èrè ilà kíkọ?
Pín
Rom 3BMYORom 3:1YCE(Yoruba Bible)
Ọ̀nà wo wá ni àwọn Juu fi sàn ju àwọn orílẹ̀-èdè yòókù lọ? Kí ni anfaani ìkọlà?
Pín
Rom 3YCE