Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 2:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Ipọnju ati irora, lori olukuluku ọkàn enia ti nhuwa ibi, ti Ju ṣaju, ati ti Hellene pẹlu
Pín
Rom 2YBCVRom 2:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìpọ́njú àti ìrora, yóò wà lórí olúkúlùkù ọkàn ènìyàn tí ń hùwà ibi: ti Júù ṣáájú, àti àwọn Helleni pẹ̀lú
Pín
Rom 2BMYORom 2:9YCE(Yoruba Bible)
yóo mú ìpọ́njú ati ìṣòro bá gbogbo àwọn tí ó ń ṣe iṣẹ́ ibi. Àwọn Juu ni yóo kọ́kọ́ kàn, lẹ́yìn náà àwọn Giriki.
Pín
Rom 2YCE