Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 2:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Fun awọn ti nfi sũru ni rere-iṣe wá ogo ati ọlá ati aidibajẹ, ìye ainipẹkun
Pín
Rom 2YBCVRom 2:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹni tí ń fi sùúrù nínú rere ṣíṣe, wá ògo àti ọlá àti àìdíbàjẹ́ ni yóò fi ìyè àìnípẹ̀kun fún.
Pín
Rom 2BMYORom 2:7YCE(Yoruba Bible)
yóo fi ìyè ainipẹkun fún àwọn tí ń fi sùúrù ṣe iṣẹ́ rere nípa lílépa àwọn nǹkan tí ó lógo, tí ó sì lọ́lá, àwọn nǹkan tí kò lè bàjẹ́.
Pín
Rom 2YCE