Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 2:20YBCV(Bibeli Mimọ)
Olukọ awọn alaimoye, olukọ awọn ọmọde, ẹniti o ni afarawe imọ ati otitọ ofin li ọwọ.
Pín
Rom 2YBCVRom 2:20BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olùkọ́ àwọn aláìmòye, olùkọ́ àwọn ọmọdé, ẹni tí ó ní ètò ìmọ̀ àti òtítọ́ òfin lọ́wọ́.
Pín
Rom 2BMYORom 2:20YCE(Yoruba Bible)
O pe ara rẹ ní ẹni tí ó lè bá àwọn tí kò gbọ́n wí, olùkọ́ àwọn ọ̀dọ́, ẹni tí ó mọ àwọn nǹkan tí ó jẹ́ kókó ati òtítọ́ tí ó wà ninu Òfin.
Pín
Rom 2YCE