Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Rom 16:13YBCV(Bibeli Mimọ)

Ẹ kí Rufu ti a yàn ninu Oluwa, ati iya rẹ̀ ati ti emi.

Rom 16:13BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ẹ kí Rufusi, ẹni tí a yàn nínú Olúwa, àti ìyá rẹ̀ àti ẹni tí ó ti jẹ́ ìyá fún èmi náà pẹ̀lú.

Rom 16:13YCE(Yoruba Bible)

Ẹ kí Rufọsi, àṣàyàn onigbagbọ ati ìyá rẹ̀ tí ó tún jẹ́ ìyá tèmi náà.