Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 15:30YBCV(Bibeli Mimọ)
Mo si bẹ̀ nyin, ará, nitori Oluwa wa Jesu Kristi, ati nitori ifẹ Ẹmí, ki ẹnyin ki o ba mi lakaka ninu adura nyin si Ọlọrun fun mi
Pín
Rom 15YBCVRom 15:30BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmí rọ̀ yín, ẹ̀yin arákùnrin àti arábìnrin, nítorí Olúwa wa Jesu Kristi, àti nítorí ìfẹ́ Ẹ̀mí, kí ẹ̀yin kí ó kún mi láti bá mi làkàkà nínú àdúrà yín sí Ọlọ́run fún mi.
Pín
Rom 15BMYORom 15:30YCE(Yoruba Bible)
Ará, mo fi Oluwa wa Jesu Kristi ati ìfẹ́ ti Ẹ̀mí Mímọ́ bẹ̀ yín pé, kí ẹ máa fi ìtara bá mi gbadura sí Ọlọrun pé
Pín
Rom 15YCE