Rom 14:18
Rom 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
nítorí ẹni tí ó bá sin Kristi nínú nǹkan wọ̀nyí ni ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ Ọlọ́run, tí ó sì ní ìyìn lọ́dọ̀ ènìyàn.
Pín
Kà Rom 14Rom 14:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ẹniti o ba nsìn Kristi ninu nkan wọnyi, li o ṣe itẹwọgbà lọdọ Ọlọrun, ti o si ni iyin lọdọ enia.
Pín
Kà Rom 14