Rom 13:12
Rom 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Òru bù kọjá tan, ilẹ̀ sì fẹ́rẹ mọ́: nítorí náà ẹ jẹ́ kí a bọ́ ara iṣẹ́ òkùnkùn sílẹ̀, kí a sì gbé ìhámọ́ra ìmọ́lẹ̀ wọ̀.
Pín
Kà Rom 13Rom 13:12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oru bukọja tan, ilẹ si fẹrẹ mọ́: nitorina ẹ jẹ ki a bọ́ ara iṣẹ òkunkun silẹ, ki a si gbe ihamọra imọlẹ wọ̀.
Pín
Kà Rom 13