Rom 12:9
Rom 12:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki ifẹ ki o wà li aiṣẹtan. Ẹ mã takéte si ohun ti iṣe buburu; ẹ faramọ́ ohun ti iṣe rere.
Pín
Kà Rom 12Rom 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Kí ìfẹ́ kí ó wà ní àìṣẹ̀tàn. Ẹ máa takété sí ohun tí í ṣe búburú; ẹ fi ara mọ́ ohun tí í ṣe rere.
Pín
Kà Rom 12Rom 12:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ki ifẹ ki o wà li aiṣẹtan. Ẹ mã takéte si ohun ti iṣe buburu; ẹ faramọ́ ohun ti iṣe rere.
Pín
Kà Rom 12