Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Rom 11:9YBCV(Bibeli Mimọ)

Dafidi si wipe, Jẹ ki tabili wọn ki o di idẹkun, ati ẹgẹ́, ati ohun ikọsẹ, ati ẹsan fun wọn

Rom 11:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Dafidi sì wí pé: “Jẹ́ kí tábìlì wọn kí ó di ìdẹ̀kùn àti tàkúté, ohun ìkọ̀sẹ̀ àti ẹ̀san fún wọn.

Rom 11:9YCE(Yoruba Bible)

Dafidi náà sọ pé, “Jẹ́ kí àsè wọn di tàkúté ati àwọ̀n, kí ó gbé wọn ṣubú, kí ó mú ẹ̀san bá wọn.