Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 11:28YBCV(Bibeli Mimọ)
Nipa ti ihinrere, ọtá ni nwọn nitori nyin: bi o si ṣe ti iyanfẹ ni, olufẹ ni nwọn nitori ti awọn baba.
Pín
Rom 11YBCVRom 11:28BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nípa ti ìyìnrere, ọ̀tá ni wọ́n nítorí yín; bí ó sì ṣe ti ìyànfẹ́ ni, olùfẹ́ ni wọ́n nítorí ti àwọn baba.
Pín
Rom 11BMYORom 11:28YCE(Yoruba Bible)
Nítorí pé àwọn Juu kọ ìyìn rere, wọ́n sọ ara wọn di ọ̀tá Ọlọrun, èyí sì ṣe yín láǹfààní. Ṣugbọn níwọ̀n ìgbà tí Ọlọrun ti yàn wọ́n nítorí àwọn baba-ńlá orílẹ̀-èdè wọn, wọ́n jẹ́ àyànfẹ́ rẹ̀ sibẹ.
Pín
Rom 11YCE