Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Rom 10:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori mo gbà ẹri wọn jẹ pe, nwọn ni itara fun Ọlọrun, ṣugbọn kì iṣe gẹgẹ bi ìmọ.
Pín
Rom 10YBCVRom 10:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí mo gba ẹ̀rí wọn jẹ́ wí pé, wọ́n ní ìtara fún Ọlọ́run, ṣùgbọ́n kì í ṣe gẹ́gẹ́ bí ìmọ̀.
Pín
Rom 10BMYORom 10:2YCE(Yoruba Bible)
Nítorí mo jẹ́rìí wọn pé wọ́n ní ìtara láti sin Ọlọrun, ṣugbọn wọn kò ní òye bí ó ti yẹ kí wọ́n sìn ín.
Pín
Rom 10YCE