Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Rom 1:3YBCV(Bibeli Mimọ)

Niti Ọmọ rẹ̀, ti a bí lati inu irú-ọmọ Dafidi nipa ti ara

Rom 1:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ní ti Ọmọ rẹ̀, ẹni tí a bí láti inú irú-ọmọ Dafidi nípa ti ara

Rom 1:3YCE(Yoruba Bible)

Ìyìn rere Ọmọ Ọlọrun tí a bí ninu ìdílé Dafidi nípa ti ara.