Ifi 9:5
Ifi 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
A sì pàṣẹ fún wọn pé, kí wọn má ṣe pa wọ́n, ṣùgbọ́n kí a dá wọn ni oró ni oṣù márùn-ún: oró wọn sì dàbí oró àkéekèe, nígbà tí o bá ta ènìyàn.
Pín
Kà Ifi 9Ifi 9:5 Bibeli Mimọ (YBCV)
A si paṣẹ fun wọn pe, ki nwọn ki o máṣe pa wọn, ṣugbọn ki a dá wọn li oró li oṣù marun: oró wọn si dabi oró akẽkẽ, nigbati o ba ta enia.
Pín
Kà Ifi 9