Ifi 2:3-4 - Compare All Versions
Ifi 2:3-4 YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti iwọ si farada ìya, ati nitori orukọ mi ti o si fi aiya rán, ti ãrẹ̀ kò si mu ọ. Ṣugbọn eyi ni mo ri wi si ọ, pe, iwọ ti fi ifẹ rẹ iṣaju silẹ.
Pín
Ifi 2 YBCVIfi 2:3-4 YCE (Yoruba Bible)
O ní ìfaradà. O ti farada ìyà nítorí orúkọ mi, o kò sì jẹ́ kí àárẹ̀ mú ọ. Ṣugbọn mo ní nǹkan wí sí ọ. O ti kọ ìfẹ́ tí o ní nígbà tí o kọ́kọ́ gbàgbọ́ sílẹ̀.
Pín
Ifi 2 YCEIfi 2:3-4 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
tí ìwọ sì faradà ìyà, àti nítorí orúkọ mi tí ó sì rọ́jú, tí àárẹ̀ kò sì mú ọ. Síbẹ̀ èyí ni mo rí wí sí ọ, pé, ìwọ ti fi ìfẹ́ ìṣáájú rẹ sílẹ̀.
Pín
Ifi 2 BMYO