Ẹ gbé Oluwa Ọlọrun wa ga, ki ẹ si ma sìn nibi òke mimọ́ rẹ̀; nitori Oluwa Ọlọrun wa mimọ́ ni.
Ẹ yin OLUWA, Ọlọrun wa, kí ẹ sì jọ́sìn níbi òkè mímọ́ rẹ̀; nítorí pé mímọ́ ni OLUWA Ọlọrun wa.
Gbígbéga ni OLúWA Ọlọ́run wa kí a sìn ín ní òkè mímọ́ rẹ̀ nítorí OLúWA Ọlọ́run wa jẹ́ mímọ́.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò