O. Daf 98:2
O. Daf 98:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oluwa ti sọ igbala rẹ̀ di mimọ̀: ododo rẹ̀ li o ti fi hàn nigbangba li ojú awọn keferi.
Pín
Kà O. Daf 98O. Daf 98:2 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA ti sọ ìṣẹ́gun rẹ̀ di mímọ̀, ó ti fi ìdáláre rẹ̀ hàn lójú àwọn orílẹ̀-èdè.
Pín
Kà O. Daf 98