O. Daf 91:15
O. Daf 91:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Òun yóò pè mí, èmi yóò sì dá a lóhùn; èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìpọ́njú, èmi yóò gbà á, èmi yóò sì bu ọlá fún un
Pín
Kà O. Daf 91O. Daf 91:15 Bibeli Mimọ (YBCV)
On o pè orukọ mi, emi o si da a lohùn: emi o pẹlu rẹ̀ ninu ipọnju, emi o gbà a, emi o si bu ọlá fun u.
Pín
Kà O. Daf 91