O. Daf 91:11
O. Daf 91:11 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí yóo pàṣẹ fún àwọn angẹli rẹ̀, nítorí rẹ, pé kí wọ́n máa pa ọ́ mọ́ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.
Pín
Kà O. Daf 91O. Daf 91:11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ti yio fi aṣẹ fun awọn angeli rẹ̀ nitori rẹ, lati pa ọ mọ́ li ọ̀na rẹ gbogbo.
Pín
Kà O. Daf 91