O. Daf 9:12 - Compare All Versions

O. Daf 9:12 YBCV (Bibeli Mimọ)

Nigbati o wadi ẹjọ-ẹ̀jẹ, o ranti wọn: on kò si gbagbe ẹkún awọn olupọnju.

O. Daf 9:12 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí ẹni tí ó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ rántí; òun kò kọ ẹkún àwọn tí a pọ́n lójú.

O. Daf 9:12 YCE (Yoruba Bible)

Nítorí olùgbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ ranti, kò sì gbàgbé igbe ẹkún àwọn tí a pọ́n lójú.