Ibinu rẹ lẹ̀ mọ mi lara kikan, iwọ si ti fi riru omi rẹ gbogbo ba mi ja.
Ọwọ́ ibinu rẹ wúwo lára mi, ìgbì ìrúnú rẹ sì bò mí mọ́lẹ̀.
Ìbínú rẹ ṣubú lé mi gidigidi; ìwọ ti fi àwọn ìjì rẹ borí mi.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò