O. Daf 86:2
O. Daf 86:2 Yoruba Bible (YCE)
Dá ẹ̀mí mi sí nítorí olùfọkànsìn ni mí; gba èmi iranṣẹ rẹ tí ó gbẹ́kẹ̀lé ọ là; ìwọ ni Ọlọrun mi.
Pín
Kà O. Daf 86O. Daf 86:2 Bibeli Mimọ (YBCV)
Pa ọkàn mi mọ́; nitori emi li ẹniti iwọ ṣe ojurere fun: iwọ, Ọlọrun mi, gbà ọmọ ọdọ rẹ ti o gbẹkẹle ọ.
Pín
Kà O. Daf 86