Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

O. Daf 75:2-3

O. Daf 75:2-3 Bibeli Mimọ (YBCV)

Nigbati akokò mi ba de, emi o fi otitọ ṣe idajọ. Aiye ati gbogbo awọn ti ngbe inu rẹ̀ warìri: emi li o rù ọwọ̀n rẹ̀.

Pín
Kà O. Daf 75

O. Daf 75:2-3 Yoruba Bible (YCE)

OLUWA ní, “Nígbà tí àkókò tí mo yà sọ́tọ̀ bá tó, n óo ṣe ìdájọ́ pẹlu àìṣojúṣàájú. Nígbà tí ayé bá ń mì síhìn-ín sọ́hùn-ún, ati gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀; èmi a mú kí òpó rẹ̀ dúró wámúwámú.

Pín
Kà O. Daf 75

O. Daf 75:2-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)

Ìwọ wí pé, “Mo yan àkókò ìyàsọ́tọ̀; Èmi ni ẹni tí ń ṣe ìdájọ́ òdodo. Nígbà tí ayé àti àwọn ènìyàn ibẹ̀ wárìrì, Èmi ni mo di òpó rẹ̀ mú ṣinṣin.

Pín
Kà O. Daf 75
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò