O. Daf 75:1
O. Daf 75:1 Yoruba Bible (YCE)
A dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Ọlọrun; a dúpẹ́. À ń kéde orúkọ rẹ, a sì ń ròyìn iṣẹ́ ribiribi tí o ṣe.
Pín
Kà O. Daf 75O. Daf 75:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
ỌLỌRUN, iwọ li awa fi ọpẹ fun, iwọ li awa fi ọpẹ fun nitori orukọ rẹ sunmọ itosi, iṣẹ iyanu rẹ fi hàn.
Pín
Kà O. Daf 75