O. Daf 73:3-4
O. Daf 73:3-4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ti emi ṣe ilara si awọn aṣe-fefe, nigbati mo ri alafia awọn enia buburu. Nitoriti kò si irora ninu ikú wọn: agbara wọn si pọ̀.
Pín
Kà O. Daf 73Nitori ti emi ṣe ilara si awọn aṣe-fefe, nigbati mo ri alafia awọn enia buburu. Nitoriti kò si irora ninu ikú wọn: agbara wọn si pọ̀.