O. Daf 73:1
O. Daf 73:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nítòótọ́ Ọlọ́run dára fún Israẹli, fún àwọn ọlọ́kàn funfun.
Pín
Kà O. Daf 73O. Daf 73:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
NITÕTỌ Ọlọrun ṣeun fun Israeli, fun iru awọn ti iṣe alaiya mimọ́.
Pín
Kà O. Daf 73