Ọlọ́run yóò bùkún fún wa, àti gbogbo òpin ilẹ̀ ayé yóò sì máa bẹ̀rù rẹ̀.
Ọlọrun yio busi i fun wa; ati gbogbo opin aiye yio si ma bẹ̀ru rẹ̀.
Ọlọrun bukun wa, kí gbogbo ayé máa bẹ̀rù rẹ̀.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò