O. Daf 61:1-2
O. Daf 61:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
GBỌ́ ẹkún mi, Ọlọrun; fiye si adura mi. Lati opin aiye wá li emi o kigbe pè ọ, nigbati o rẹ̀ aiya mi, fà mi lọ si apata ti o ga jù mi lọ.
Pín
Kà O. Daf 61GBỌ́ ẹkún mi, Ọlọrun; fiye si adura mi. Lati opin aiye wá li emi o kigbe pè ọ, nigbati o rẹ̀ aiya mi, fà mi lọ si apata ti o ga jù mi lọ.