Gbà mi lọwọ awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ, ki o si gbà mi silẹ lọwọ awọn enia-ẹ̀jẹ.
Gbà mí lọ́wọ́ àwọn aṣebi, kí o sì yọ mí lọ́wọ́ àwọn apànìyàn.
Gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníṣẹ́ búburú kí o sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ènìyàn tí ń pòǹgbẹ ẹ̀jẹ̀.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò