O. Daf 56:7 - Compare All Versions

O. Daf 56:7 YBCV (Bibeli Mimọ)

Nwọn ha le ti ipa aiṣedede là? ni ibinu, bi awọn enia na lulẹ̀, Ọlọrun.

O. Daf 56:7 YCE (Yoruba Bible)

Nítorí náà, san ẹ̀san ẹ̀ṣẹ̀ wọn fún wọn; ninu ibinu rẹ, Ọlọrun, ré àwọn eniyan yìí lulẹ̀.

O. Daf 56:7 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

San ẹ̀san iṣẹ́ búburú wọ́n fún wọn; ní ìbínú rẹ, Ọlọ́run, wọ́ àwọn ènìyàn náà bọ́ sílẹ̀.