O. Daf 56:4
O. Daf 56:4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nipa Ọlọrun li emi o ma yìn ọ̀rọ rẹ̀, Ọlọrun li emi o gbẹkẹ mi le, emi kì yio bèru: kili ẹran-ara le ṣe si mi.
Pín
Kà O. Daf 56O. Daf 56:4 Yoruba Bible (YCE)
Ọlọrun, mo yìn ọ́ fún ọ̀rọ̀ rẹ, ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé láìbẹ̀rù; kí ni eniyan ẹlẹ́ran ara lè fi mí ṣe?
Pín
Kà O. Daf 56